LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Àṣẹ

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Hemyķul on the beat
I fit never get today
But e sure me say me go get tomorrow
I wanna leave this stage
Before e too late
Make dem no see me less o
Mo dé tún strive
Mo grind
Mo ṣáṣé
Bóyá ọmọ ọba gọ́n lè ṣọ́ lọ́lá
Gba log in
Je loading
Je C,C
Lo Paris o
Co, Coz
Mo ní láti, láti lọ́wọ́
Ajé yìí kò wáà mí rí o
Ìrè mi kò wáà mí rí o
Owó gọ́n kò wá mí rí o
Wá mí rí o

Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa ló̩wó̩ lówó̩
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa kọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa bí ọmọ lẹ́mọ̀
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa kọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀
Àṣẹ
Olówó ṣá ló ń pé láyé
Orí, dakun wá gbé mí o
Dàkùn, dàkùn wá gbé mí o
Orí ìyá mi kò tẹ̀ mí o
Àpò ṣàṣàmúrà gọ́n ò kí ń gbé o
Kí má yá ọ̀tòṣì láyé tó mò wà
I wan go gand lo faaji
Plenty, plenties for my mummy
Ẹlẹ́dàá mi, jọ ṣàánú mí o
Orí mi, dakun wá gbé mí o
Wá gbé mí o
Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Ẹ bá mi pé Àṣẹ o
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa ló̩wó̩ lówó̩
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa kọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa bí ọmọ lẹ́mọ̀
Àṣẹ
Gbogbo wa la máa kọ́lẹ̀ mọ́lẹ̀
Àṣẹ

WRITERS

Olaosebikan Precious

PUBLISHERS

Lyrics © O/B/O DistroKid

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Enjoyment

Sentiment
Thumbsup Icon
Theme

Gender identity and Sexual Orientation