LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

AṢẸNI

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Ta Aṣẹni fin ṣẹ ra ẹ lọpọ
Kọdẹ mọ mọ
Ẹni tọbee lọ tara ẹ lọpọ
Ẹlẹbọtọ
Ọrin di ọwọ Ọrin di ọla
Ọri mi dakun jẹ kin laa
Malọ ji iṣẹ fun ẹni tọ ti laa
Tin ba sẹ iṣẹ kin ma sẹ asẹ la
Akabi kaula da kun kabi da
Ọri
Ọri mi ma ta kọ mi
Ẹbẹ ni mọ be Ọri
Ọri mi dakun gbẹ mi
Mi ọ gbọọ rii
Ki ẹlẹgan malọ yọọ mi
Ababọ Ọri
Fi ọrisa si lẹ ka bọ Ọri
Ẹlẹda mi
Shẹgbẹ lẹyin mi
Ọni nbi ọla
Ẹnikẹni
Rọ 'iku rọ mi
Kọde ni ri ọla
Ẹlẹda mi
Shẹgbẹ lẹyin mi
Ọni nbi ọla
Ẹnikẹni
Rọ 'iku rọ mi
Kọde ni ri ọla
Ẹpa n para ẹ
Ọ ni ọun pa aja
Dindinrin ga ra ẹ
Ọ ni ọun ga wa
Aṣẹni sẹ ira ẹ
Ọ ni ọun sẹ ara
Bobo be yourself
Ma fi ọ wọ e sẹ ra ẹ pa
Ẹpa n para ẹ
Tọba fi ọ wọ sẹ ra ẹ
Kọ kan mi sorry
Wẹyẹr lọ ya ara ẹ
Kọ fẹ sẹ isẹ ọfẹ gba ọwọ
No food for lazy
And I fit Dey look
Like I no see
Tẹmi lọba mi
Ẹni mọ ija lọ mọ isaa
Kọ n sẹ ẹru lọn ba mi
Ẹlẹda mi
Shẹgbẹ lẹyin mi
Ọni nbi ọla
Ẹnikẹni
Rọ 'iku rọ mi
Kọde ni ri ọla
Ẹlẹda mi
Shẹgbẹ lẹyin mi
Ọni nbi ọla
Ẹnikẹni
Rọ 'iku rọ mi
Kọde ni ri ọla

WRITERS

Olalekan Ajibola

PUBLISHERS

Lyrics © O/B/O DistroKid

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Enjoyment

Sentiment
Thumbsup Icon
Theme

Coarse Language