Bi o lowo lowo ti o kole mole (Vanity)
Bi o kole mole ti o rale mole (Vanity)
Bi o lowo laye ile aye ogun (Vanity)
Bo o lowo lowo aye wahala (Vanity)
Ore ronu re ki o ranti pe
Bi o lowo laye ranti ojo iku (Vanity)
Ojo to ba ku ni gbogbo re a pin (Vanity)
Bi o ba logbon, bi o ba lola (Vanity)
Bi o wa nipo fun'gba die ni (Vanity)
O ba ronu re ki o ranti pe
Ojoojumo aye lo nsare ka (Vanity)
O nsare ka nitori owo (Vanity)
Owo lo nwa o ko wa Olorun (Vanity)
Ile aye asan ile aye iro (Vanity)
K'o to di p'o pe maa ranti pe
Ranti olowo ti won ti rekoja (Vanity)
Ranti omowe ti won je gbajumo (Vanity)
Ranti ologbon to gbo koja ogbon (Vanity)
Ojo won ku ni gbogbo re dopin (Vanity)
Ojoojumo aye maa ranti pe
Where will you spend eternity
Where will you spend eternity
Where will you spend eternity
Where will you spend eternity
Where will you spend eternity
Where will you spend eternity