LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Ìgbà kìí lo bí òréré

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Igba kiilo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon
Igba kiilo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon

Ah aye asan
Asan ma l'aye yi o
Igba kii lo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon

Gba Jesu gbo iwo ore mi
Gba Jesu l'Oluwa aye re loni
Tori iku lee de lola
Loni l'Olugbala npe o
Asan l'aye

Ah, aye asan
Asan ma l'aye yi o
Igba kii lo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon

Awon olowo ana da
Awon olola ana da loni
Igba won ku aye gbagbe won
Ile aye yi ko je nkan
Asan l'aye

Ah aye asan
Asan ma l'aye yi o
Igba kii lo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon

Ipo ola ti o wa loni
Ebun Oluwa ni ore mi
Kiise nipa ogbon re
Ohun ti o ni t'Oluwa ni
Asan laye

Ah aye asan
Asan ma l'aye yi o
Igba kii lo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon

Gbogbo ohun ti a nse loni
Itan ni yo da bo d'ola o s'e mo
Kinni ki won so pe o gbe se
Bo ba fi ku gbogbo re dopin
Asan l'aye

Ah aye asan
Asan ma l'aye yi o
Igba kii lo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon

Rora jaye iwo ore mi
Ranti Eleda re nigba t'o wo
B'aye ba ja o ko se so
Ile aye fun gba die ni
F'aye re fun Jesu loni
Asan l'aye

Ah aye asan
Asan ma l'aye yi o
Igba kii lo bi orere o
Aye ki ito bi opa ibon

WRITERS

David Adesina

PUBLISHERS

Lyrics © O/B/O DistroKid

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Sadness

Sentiment
Thumbsup Icon
Theme

Race and ethnicity