LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Kí ni iṣẹ́ rẹ fún OLÚWA

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Àwé lẹ̀ẹ́
Mi dúwe lẹ̀ẹ́
Ka'bẹ́nẹ ati yá ṣèyí sí
Ọ dúwe dáwó
Uwé dá
Ọ dúwe kọrin
Uwé kọ

You sidon dey look
To give you no gree
To shake bodi, money you no give
Make you join for worship
You no gree sing
Wetin you go give
Wetin you bring

Kí ni'ṣẹ́rẹ wún Olúwa
Kí ni'ṣẹ́rẹ wún Olúwa
Ọ dúwe dáwó
Uwé dá
Ọ dúwe kọrin
Uwé kọ
Wo gbọ́wọ́ lágbọ̀n
Wèé wawò
Kí ni'ṣẹ́rẹ wún Olúwa

Kí ni iṣẹ́ rẹ fún Olúwa
Ani, kí ni iṣẹ́ rẹ fún Elédùmarè
Ní torí wọ́n ní k'odáwó
O l'óòdá
Wọ́n ní kí o kọrin
O l'óòkọ
O kàn gbọ́wọ́ láhọ́n
Ò nwòran
Ngbọ́, kí ni iṣẹ́ rẹ fún Elédùmarè gan gan nán
Kí ni ànfàni rẹ l'ọ́dọ̀ ẹlẹ́ẹ̀dá rẹ

Àwé lẹ̀ẹ́
Mi dúwe lẹ̀ẹ́
Ka'bẹ́nẹ ati yá ṣèyí sí
Ọ dúwe dáwó
Uwé dá
Ọ dúwe kọrin
Uwé kọ

You sidon dey look
To give you no gree
To shake bodi, money you no give
Make you join for worship
You no gree sing
Wetin you go give
Wetin you bring

Kí ni'ṣẹ́rẹ wún Olúwa
Kí ni'ṣẹ́rẹ wún Olúwa
Ọ dúwe dáwó
Uwé dá
Ọ dúwe kọrin
Uwé kọ
Wo gbọ́wọ́ lágbọ̀n
Wèé wawò
Kí ni'ṣẹ́rẹ wún Olúwa

WRITERS

Emenike Enete, Traditional-Ọ̀wọ̀ Chorus

PUBLISHERS

Lyrics © O/B/O DistroKid

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Enjoyment

Sentiment
Thumbsup Icon
Theme

None