LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

Ará Ẹdìde Ẹbámi Jó

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Ará ẹ dìde, k'ẹbámi jó
Ènìyàn mi, ẹ bámi yọ̀
Olúwa mi l'ógbé mi ga

Ará ẹ dìde, k'ẹbámi jó
Ènìyàn mi, ẹ bámi yọ̀
Olúwa mi l'ókó mi yọ

Ó f'ire gbogbo dámilọ́lá
Ó f'ohun rere múnú mi dùn
Kí lótún yẹmí bí kòṣe ọpẹ́
Opẹ́ ni tèmi lọ́jọ́ gbogbo

Ará ẹ dìde, k'ẹbámi jó
Ènìyàn mi, ẹ bámi yọ̀
Olúwa mi l'ókó mi yọ

Nínú ewu gbogbo, ó pamí mọ́
Nínú ewu gbogbo, ó mú mi yè
Kí lótún yẹmí bí kòṣe ọpẹ́
Opẹ́ ni tèmi lọ́jọ́ gbogbo

Ará ẹ dìde, k'ẹbámi jó
Ènìyàn mi, ẹ bámi yọ̀
Olúwa mi l'ókó mi yọ

Mo ti f'ojojúmọ́ mu ọtí rí
Fífagbó fa sìgá kò kẹ́yìn níbẹ́
Bíbọ́ tí mobọ́ Jésù nìkan lóyé
Opẹ́ ni tèmi l'ọ́jọ́ gbogbo

Ará ẹ dìde, k'ẹbámi jó
Ènìyàn mi, ẹ bámi yọ̀
Olúwa mi l'ókó mi yọ

Ó f'ọmọ rẹ̀ kan ṣoṣo dá wa lọ́lá
Ó fi ṣètùtù kí a lè yè
Bó tilẹ̀ jẹ́pé ẹlẹ́ṣẹ̀ ni wá
Ífẹ́ rẹ̀ pọ̀si lọ́jọ́ gbogbo

Ará ẹ dìde, k'ẹbámi jó
Ènìyàn mi, ẹ bámi yọ̀
Olúwa mi l'ókó mi yọ

Ará ẹ dìde, k'ẹbámi jó
Ènìyàn mi, ẹ bámi yọ̀
Olúwa mi l'ógbé mi ga

WRITERS

Emenike Enete, Traditional-Yoruba Original-Chorus

PUBLISHERS

Lyrics © O/B/O DistroKid

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other

LyricIQ Analysis

Top Emotion

Enjoyment

Sentiment
Thumbsup IconThumbsup IconThumbsup Icon
Theme

Gender identity and Sexual Orientation