LyricFind Logo
LyricFind Logo
Profile image icon
Lyric cover art

WÓN DÉ

Apple Music logo
Deezer logo
Spotify logo
Lyrics
Chorus:
Wọ́n dé e
Àwọn 'oní fìlà gẹn-gẹ
Wọ́n dé
Áwọn oní gèlè ya-ya
Wọn túntì dé
Pèlu agbádá wọn ò
Wón dé
Aláso òkè won de

Verse 1:
Ti wọn ló ma ń pò jù
Níbi wọ́n tií n ṣe fáàrí
Ṣùgbọ́n Ókan ni l'ómi inú
Pé áwọn wọ̀n yí ọ
Ni wọ́n n pe Alálèe wọn láláìda
Ẹ bá mì bi wọ́n
Ní bo lọ̀ n rò pé
fáàrí wọ́n ti wá?

Chorus Repeat

Verse 2:
Tí wọn ló ma ń pọ̀ jù
Níbi wọ́n tiín yangàn oúnjẹ
Sùgbọ́n Ókan ni l'ómi inú
Pé áwọn wọ̀n yi o
Ni wọ́n gbé babàńla wọn ṣépè o ò
Ẹ bá mi bi wọ́n o
Níbo lọ́ n ròpé
Onje wón ti wá?

***Add Lips***

Chorus Repeat and fades

WRITERS

Ayobami Adedamola, Olufemi "Afonrere", Toju Sunmola

PUBLISHERS

Lyrics © Gotright Innovations Ltd

Share icon and text

Share


See A Problem With Something?

Lyrics

Other